Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Ioni
je
atomu
tabi
horo
kan ni inu ibi ti iye apapo awon
elektronu
ko dogba mo iye apapo awon
protonu
, bi be ti atomu na yio ni
agberu itanna
to seku to je didaju tabi lilodi.
Ioni
wa lati oro ede
Griiki
??ν (to tumosi "o rinso"), o si koko je lilo latowo asefisiksi
Michael Faraday
fun awon ohun ti won unlo labe iwo itanna larin awon
elektrodu
ninu iyosomi kan, nigbati
ayika itanna
kan ba je mimulo mo.
Ti atomu adogba kan ba pofo elektronu kan tabi jubelo, yio ni agberu siseku didaju, eyi ni a unpe ni
kationi
. Ti atomu kan ba jere elektronu, yio ni agberu siseku lilodi, a si unpe ni
anioni
. Ioni kan to ni atomu kan soso ni a unpe ni ioni atomu tabi
oniatomukan
; to ba ni atomu meji tabi jubelo, a unpe ni ioni
onihoro
tabi
oniatomupupo
.
Ninu apere isodiioni efuufu kan, awon ohun kan ti a unpe ni "ibeji ioni" je dida ti won ni elektronu adawa kan ati ioni didaju kan.