Ipinl?? Edo

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
(Atunjuwe lati Ipinl?? ?do )
Ipinl?? Edo
State nickname : Heart Beat of Nigeria
Location
Location of Edo State in Nigeria
Statistics
Governor
( List )
Adams Oshiomhole ( AC )
Date Created 27 August 1991
Capital Benin City
Area 17,802 km²
Ranked 22nd
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 27th
2,159,848
3,497,502
ISO 3166-2 NG-ED
imura omo ilu ipinle Edo

Ipinl?? Edo j?? ??kan ninu aw?n ipinl?? m??rindinlogoji ni oril?? ede Naijiria , ti o wa ni agbegbe ?ku guusu ti oril?? ede naa. [1] G??g?? bi abajade eto-ikaniyan loril?? ede ti ?dun 2006, ipinl?? naa j?? ipinl?? ?l????k?rindinl??gb??n ni iye p??lu eniyan ti o to mili??nnu m??ta-ab??-dinni-di?? ni oril?? ede Naijiria . [2] Ipinl?? Edo j?? ipinl?? ?l????kejilelogun ti o gbooro jul? ni aaye tabi agbegbe g??g?? bi titobi il?? ni oril?? ede Naijiria . [3] Olu-ilu ipinl?? naa ati ilu re, ni Ilu Benin , ti o j?? ilu ?l????k??rin ti o tobi jul? ni oril?? ede Naijiria , ti o si j?? ibudo ile-i??? ti ? ?e r??ba oril?? edey. [4] [5] W??n daa sil?? ni ?dun 1991 latara Ipinl?? Bendel t??l??ri, w??n si tun m???? si iro ?kan oril?? ede. [6] Ipinl?? Edo pin aala p??lu Ipinl?? Kogi si ariwa-ila-oorun, p??lu Ipinl?? Anambra si ila-oorun, p??lu Ipinl?? Delta si guusu-ila-oorun ati guusu-guusu ati p??lu Ipinl?? Ondo si iw??-oorun. [7]

Aw?n aala ode-oni ti Ipinl?? Edo yi aw?n agbegbe ti w??n j?? agbegbe ori?iri?i ij?ba ati ij?ba ti w??n dasil?? ni ?g??run ?dun m??kanla AD s?yin ka, iy?n Ij?ba Benin . [8] Ilu atij?? ti Edo , agbegbe ti ilu Benin ode-oni, j?? ile si di?? ninu aw?n i???-oril?? ti o tobi jul? ni agbaye. [9] Ni ?dun 1897, ij?ba alaw??-funfun ?e irin-ajo ijiya ti agbegbe kan, ti o pa pup?? ninu aw?n ilu Edo atij?? run ati ?i?afikun agbegbe naa sinu ohun ti yoo di guusu Naijiria lab?? abo ij?ba alaw??-funfun . [10] [11]

Ipinl?? Edo j?? ipinl?? ti o kunfun aw?n ori?iri?i aw?n olugbe ti o gbil?? j?? aw?n ara Edoid , p??lu aw?n ara Edo (or Bini) , [12] Esan , Owan ati Afemai people . [13] EdeEdoid ti o w??p?? ni sis? jul? ni ede Edo , ni eyi ti w??n maa ? s? ju ni ilu Benin. [14] ??sin kiit??ni ni o gbil?? ju ni Ipinl?? Edo. Aw?n arinrinajo onigbagb?? Portuguese ni w??n mu wa si agbegbe naa ni gbedeke ?g??run ?dun m????dogun . W??n ?e ??sin Musulumi ati ??sin abalaye naa. [15]

Aw?n ij?ba ibil?? lab?? r? [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Aw?n ij?ba ib??l?? mejidinlogun lo wa lab?? ipinl?? Edo.

  • Akoko-Edo
  • Egor
  • Esan Central
  • Esan North-East
  • Esan South-East
  • Esan West
  • Etsako Central
  • Etsako East
  • Etsako West
  • Igueben
  • Ikpoba-Okha
  • Oredo
  • Orhionmwon
  • Ovia North-East
  • Ovia South-West
  • Owan East
  • Owan West
  • Uhunmwonde

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. "Edo | state, Nigeria" . Encyclopedia Britannica (in Ede G????si) . Retrieved 2021-09-16 .  
  2. "Nigeria Census - Nigeria Data Portal" . nigeria.opendataforafrica.org . Retrieved 2021-07-08 .  
  3. "World Gazetteer: Nigeria - administrative divisions (per geographical…" . archive.ph . 2013-01-05. Archived from the original on 2013-01-05 . Retrieved 2022-05-12 .   Unknown parameter |url-status= ignored ( help )
  4. "Benin City | History & Facts" . Encyclopedia Britannica (in Ede G????si) . Retrieved 2021-07-09 .  
  5. admin (2018-06-08). "Obaseki Revives N5.1bn Urhonigbe Rubber Plantation" . THISDAYLIVE (in Ede G????si) . Retrieved 2021-07-10 .  
  6. "Edo state: The heartbeat of the Nation" . Channels Television . Retrieved 2022-08-14 .  
  7. "Edo | state, Nigeria | Britannica" . www.britannica.com (in Ede G????si) . Retrieved 2022-07-24 .  
  8. Strayer 2013 , pp. 695-696.
  9. Koutonin, Mawuna (2016-03-18). "Story of cities #5: Benin City, the mighty medieval capital now lost without trace" . the Guardian (in Ede G????si) . Retrieved 2021-03-15 .  
  10. Obinyan, T. U. (September 1988). "The Annexation of Benin". Journal of Black Studies (Sage .) 19 (1): 29?40. doi : 10.1177/002193478801900103 . JSTOR   2784423 .  
  11. Koutonin, Mawuna (2016-03-18). "Story of cities #5: Benin City, the mighty medieval capital now lost without trace" . the Guardian (in Ede G????si) . Retrieved 2021-07-10 .  
  12. "Edo" (PDF) . Archived from the original (PDF) on 2020-05-30.   Unknown parameter |url-status= ignored ( help )
  13. Refugees, United Nations High Commissioner for. "Refworld | Nigeria: Esan ethnic group; whether it is a sub-group of the Yoruba; religions practised; whether members of this ethnic group engage in Ogboni practices" . Refworld (in Ede G????si) . Retrieved 2021-03-15 .  
  14. "Edo language, alphabet and pronunciation" . omniglot.com . Retrieved 2021-03-15 .  
  15. "Benin kingdom/Edo state Religions" . www.edoworld.net . Retrieved 2021-03-15 .