한국   대만   중국   일본 
Igbaja aw?n is??gbe oorun kekere - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Igbaja aw?n is??gbe oorun kekere

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Igbaja ast??r??idi gbaungba (o han p??lu aw?? funfun) wa laarin aw?n igbayipo Mars ati Jupiter .

Igbaja aw?n is??gbe oorun kekere j?? awo roboto ti o wa lara eto idarisi oorun ti o ?akoj?p?? oorun ati aw?n ohun ti o ? yii po, ti o wa ni bii aarin iyipo Mars ati Jupiter . Aw?n akoraj? oniruuru ti ko duro deede ti w??n ? pe ni ast??r??idi tabi aw?n is??gbe oorun kekere lo gba inu r??. W??n tun maa ? pe igbaja aw?n is??gbe oorun kekere ni ojulowo igbaja aw?n is??gbe oorun kekere tabi ojulowo igbaja lati j?? ki iyat?? wa laaarin r?? ati aw?n miran ti w??n wa lagbo eto idarisi oorun ti o ?akoj?p?? oorun ati aw?n ohun ti o ? yii po bii Awon asteroidi itosi Aye ati awon asteroidi troja . [1]

Aw?n it??kasi [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

  1. Matt Williams (2015-08-23). "What is the Asteroid Belt?" . Universe Today . Retrieved 2016-01-30 .  

[1]

  1. "Mars: An Introduction to its Interior, Surface and Atmosphere" . Google Books . 1956-07-03 . Retrieved 2018-05-15 .