Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
Adak?:Wiktionary
Ede iw?? oorun Jamini (a West Germany language) ti o waye lati ara D????ji (Dutuh) ni eleyii ti w??n ? s? ni Gusu Aafirika.
Aw?n ti o ? s? ?? to mihi??nu m??fa. W??n ? s? ?? ni Namibia, malawi, Zambia ati Zimbabwe.
Aw?n kan ti o si ti ?e atipo l? si il?? Australia ati Canada naa ? s? ede naa. W??n tun maa ? pa ede yii ni keepu D???ji (lapa Dutch).
Ede aw?n ti o wa t? il?? Gusu Aafirika do ni ????turi k?tadinlogun (17th century) ni ?ugb??n o ti wa yat?? si ede D????ji (Dutch) ti il?? Uroopu (Europe) bayii nitori ede adugbo k????kan ti ? w? inu r??.
Ede yii ni ede ti o le ni idaji aw?n funfun ti o do si Gusu Aafirika ? s?. Ida aad??sa n-an aw?n ti obi w?n j?? ??ya meji ni o si ? s? ede yii p??lu.
Lati ?dun 1925 ni w?n ti ? lo ede yii p??lu ede G????si g??g?? bi ede ij?ba. Ede yii tin i litires??.
Ak?t?? Romaanu ni w??n fi ? k? ??.