한국   대만   중국   일본 
Alj??bra onigb?r? - Wikipedia, iwe-im?? ??f?? Jump to content

Alj??bra onigb?r?

Lat'?w?? Wikipedia, iwe im?? ??f??
A line passing through the origin (blue, thick) in R 3 is a linear subspace, a common object of study in linear algebra.

Aljebra gbigboro (linear algebra) je eka imo isiro ti o ni se pelu imo nipa awon atokaona (vector), aaye atokaona (vector space), maapu gbigboro (linear map) ati awon ona-eto idogba gbigboro (system of linear equation). Aaye atokaona se pataki ninu imo isiro ayeodeoni, nipa bayi aljebra alatele wulo lopolopo ninu aljebra afoyemo ati agbeyewo alabase (functional analysis). O tun wulo gidigidi ninu awon sayensi aladabaye ati sayensi awujo nigba t'oje pe awon apere alainitele (nonlinear) se mu sunmo eyi to je alatele (linear).

Itan Alj??bra gbigboro [ atun?e | atun?e ami??r?? ]

Itan aljebra ayeodeoni bere ni arin odun 1843 ati 1844. Ni odun 1843, William Rowan Hamilton (eni ti o koko soro nipa atokaona ) se awari quaternions . Ni odun 1844, Hermann Grassmann ko iwe ni ede Germani pelu akole Die lineale Ausdehnungslehre . Arthur Cayley mu apotinomba (matrix) wa ni odun 1857. Ilana Cramer to n fihan wa bi a se le s'ojutu awon idogba iseyato abo (partial differential equation) lo so aljebra alatele di eko ti a n ko ni awon ile-eko giga. Fun apere, E.T. Copson ko pe:

Ni odun 1922 ti mo di oluko kekere ni ile-eko giga Edinburgh, o yamilenu lati ri pe ilanaeto eko yato si ti ile-eko giga Oxford. Eka bi isodiodidi Lebesgue (Lebesgue integration), ero apotinomba (matrix theory), agbeyewo aminomba (numerical analysis), alawonile Riemannian (Riemannian geometry), lori awon eyi ti n ko mo nkankan nipa won.... E.T. Copson, Oro Isaju si Idogba Iseyato Abo , 1973